Orọ asiri yii jẹmọ ayelujara Microsoft, awọn ise ati oja to n gba data ti o si nse afihan awọn ala, pelu awọn isẹ aikilẹhin ti ko si loju ila Ko jẹmọ awọn ojula Microsoft, isẹ ati oja ti kii se afihan tabi somọ ọrọ tabi ti o ni ọrọ asiri ti wọn
Jọwọ ka awọn ọrọ kukuru isale ki o tẹ ‘’Kosi’’ fun alaye sii lori koko ọrọ kan. O tun le yan lati ara ọja to’wa loke lati wo ọrọ asiri ọja. Awọn ọja miiran, ise tabi awọn iwo oju ti a darukọ ninu ọrọ yii le ma wa ni awọn ọja. O le ri awọn irohin sii lori idasi ọrọ Microsoft nipa idabobo asiri rẹ ni http://www.microsoft.com/privacy.
Opo ojula Microsoft nlo "kukisi", faili atejise kekere ti ayelujara le ka ninu ako ti o fi kukisi si ori dirafu re. A le lo kukisi lati se ipamo ayoo ati setin re; iranwo iwole; ipese ipolowo tani lokan; ati atupale ise ojula.
A tun nlo beakoni ojula lati ran o lowo lati pin kukisi ati sakojo atupale. Eyi le pelu beakoni ojula egbe keta, eyi ti a ko faye gba lati gba iwifun eleni re.
Oni orisii irinse lati sakoso kukisi ati irufe imo ero, pelu:
Bi A Ti Nlo Awon Kuki
Opo ojula ayelujara Microsoft nlo "kukisi" eyi ti o je ọrọ kekere ti a fisi ori disiki lile rẹ lati ọwọ onipin ayelujara. Kukisi ni awọn iwifun ti a le ka bobaya lọwọ onipin ayelujara ninu aaye ti o fun ọ ni kukisi. Atejise yii saba maa n ni okun oniruuru nomba ati leta ti o se adamo komputa re, sugbon o le ni awon iwifun miiran pelu. Eyi ni apẹẹrẹ irufẹ ikọwe ti a fi pamọ si kuki ti Microsoft le fi si ori hádi dirafù rẹ nigba ti o ba bẹ ọkan lara ayelujara wa wo: E3732CA7E319442F97EA48A170C99801
Ale lo awon kuki fun:
Awọn kan ninu kuki yii ti a saba maa nlo ni o wa ni atẹ yii. Àtòkọ o tan sibẹ, ṣugbọn o wa lati ṣalaye lara idi ti a fi ngba awon kuki. Bi o ba ṣe abẹwo si ọkan ninu awọn ayelujara wa, ojula le ṣe agbekalẹ lara tabi gbogbo awọn kuki yii:
Ni afikun pelu kukisi ti Microsoft le ssagbekale nigba ti o ba be ayelujara wo, egbe keta le se agbekale kukisi lori dirafu lile re nigba ti o ba be ojula Microsoft wa. Nigba miiran, nitori pe a ti be egbe keta lowe lati se ipese awon ise kan fun wa, gegebi atupale ojula. Nigba miiran, nitori pe ayelujara wa ni awon akoonu kan tabi ipolongo lati odo egbe keta, gegebi fidio, irohin tabi ipolongo ti netiwoki onipolongo miiran se. Nitori pe burausa re somo olupese safa ojula awon egbe keta yii lati gba akoonu yii, awon egbe keta yii le se agbekale tabi ka kukisi won lori dirafu lile re.
Ilana Iṣakoso Kuki
Fun apẹẹrẹ, ni Internet Explorer 9, o le di kuki nipa igbese wọnyii:
Ilana didi kukisi ni awon burausa miiran wa ni http://www.allaboutcookies.org/manage-cookies/.
Jọwọ mọ pe bi o ba yan lati di kuki, ole male ṣe atẹwọle tabi lo awọn eroja miiran ti a fihan ni ojula Microsoft ati iṣẹ ti o da lori kuki, ati awọn ipolowo ti o da lori kuki ni a le ma bọwọfun.
Fun apeere, ni Internet Explorer 9, o le di kukisi pa nipa gbigbe igbese wonyii:
Ilana fun ipare kuki ni awọn burausa miiran wa ni http://www.allaboutcookies.org/manage-cookies/.
Jọwo ri mọ daju pe bi o ba yan lati pa awon kuki rẹ, sẹtin ati iṣakoso aayo lọwọ kuki naa, ati ayoo ipolowo, ni yoo parẹ o si le nilo atunda.
Iṣakoso Burausa Fun ''Maṣe Tẹlọrọ'' ati Idabobo Itẹlọrọ. Awọn burausa titun kan ni aṣemọ abuda ''Maṣe Tẹlọrọ''. Ọpọ awọn abuda yii, nigba ti a ba tan wọn, nfi ami tabi awọn ibuyifun ranṣẹ si ayelujara ti o bẹwo lati fihan pe o ko fẹ ki a tẹlọrọ rẹ. Awọn ojula yii (tabi akoonu ojula ẹgbẹ kẹta) le maa ṣiṣẹ lori ohun ti o yẹwo gẹgẹbi itẹlọrọ bi o tilẹ jẹpe o ti safihan awọn ibuyifun, eyi da lori iṣe ipamọ ojula yii.
Internet Explorer 9 ati 10 ni awọn abuda ti a peni Idabobo Itẹlọrọ ti o nṣe iranwọ fun didẹkun ayelujara ti o lọ lati maa fi nipa rẹ ranṣẹ si olupese ẹgbẹ kẹta. Nigba ti o ba safikun Àtòkọ Idabobo Itẹlọrọ, Internet Explorer yoo di akoonu ẹgbẹ kẹta, pẹlu kuki, lati ayelujara ti a darukọ gẹgẹbi ojula ti a gbọdọ di. Nipa didẹkun ipe sori ojula yii, Internet Explorer yoo dẹkun ifitonileti ti ẹgbẹ kẹta yii le gba lati ọdọ rẹ. Nigba ti o ba sini Àtòkọ Idabobo Itẹlọrọ ti o nṣiṣẹ, Internet Explorer yoo fi ami Mase Teloro ranṣẹ tabi awọn ibuyifun si awọn ayelujara ti o lọ. Lafikun, ni Internet Explorer 10 o le yisi DNT ''pa'' tabi ''tan'' latinuda, bi o ba fẹ. Si nipa iwifun nipa aabo Titele ati bi a o se ri won, jowo wo Oro asiri Internet Explorer tabi Iranwo Internet Explorer.
Ile ise onipolowo lokookan le se ipese ijade lona ti o seese pelu opo imugboro ipolongo yiyan. Fun apeere, aayo ipolongo microsoft ati isakoso ijade ni a le ri ni http://choice.live.com/advertisementchoice/. Jowo mo daaju pe jijade o tunmo sipe o koni gba ipolongo tabi ri ipolongo mo; sugbon, bi o ba jade, ipolongo ti waa ri gba koni je onise afokansi. Ni afikun, jijade koda ifitonileti duro lati ma lọ si apèsè wa, ṣugbọn o nda iṣẹda ati imugbooro nipa ẹni duro ti a le lo fun ipolowo ihuwasi.
Ilo Beakoni Ojula Wa
Oju ewe ojula Microsoft leni awon aworan ẹrọ ti a mọsi beakoni ojula - ti a maa n pe ni ẹyọ-pisẹli gifu - ti o le ranwa lọwọ lati ṣe agbekalẹ kuki l'ojula wa, o njẹ ki a ka oluṣamulo ti o ti ṣe abẹwo si awon oju ewe yen ti o si ṣe ifijise awọn iṣẹ akanṣe. Ale safikun ayelujara beakoni ninu ipolongo ise e-maili tabi lẹta oniroyin wa lati le mo boya ati si isẹ tabi sise le lori.
Atunle ṣiṣẹ pẹlu awọn ile iṣẹ miiran ti o nṣe ipolowo lori ojula Microsoft lati fi beakoni ojula sori ojula wọn tabi si ipolowo wọn lati le jẹ ki a ṣe imudagba itupalẹ nipa igba ti a ṣe atẹwọle ni ipolowo kan ni esi ojula Microsoft ni rira tabi iṣe miiran lori ojula olupolowo.
Lakotan, Ojula Microsoft le gba ayelujara beakoni fun egbe keta lati ranwa lọwọ lati se awari iwulo si ipolongo wa tabi ise ojula wa miiran Awon ojula beakoni yii le fayegba egbe keta lati sagbekale tabi ka kukisi lori komputa re Ako fayegba egbe keta lati lo beakoni ayelujara lori ojula wa lati gba tabi wo iwifun re. Laisani ani, o le jade kuro ni gbigba data tabi ilo lowo atupale ile ise egbe keta nipa tite asopo fun okookan atupale olupese yii:
Imo ero to jora miiran
Ini afikun pelu ojulowo kukisi ati beakoni ojula, ayelujara lelo imo ero miiran lati sapamo ati ka faili lori komputa re. Ale se eyi lati sabojuto aako re tabi mu iyara wa ati ise nipa titoju awon faili kan ni tibile. Sugbon, gegebi ojulowo kukisi, atunle lo lati sapamo idamo ara oto fun komputa re, eyi ti a le lo lati tele ihuwasi. Awon imo ero yii je lara Ohun Pipin Ibile (tabi "Itan kukisi") ati ohun elo ikojo Silverlight.
Ohun Pipin Ibile tabi "Itan kukisi". Ayelujara ti o nlo imo ero Itan Adobe le lo ohunpipin ibile tabi ‘’Itan kukisi’’ lati toju data sori komputa re. Sakiyesi pe agbara lati samukuro Itan kukisi leje tabi maje eyi ti setin burausa re se akoso re fun ojulowo kukisi niwon igba ti eyi le yato lati burausa si ara. Lati roralo tabi di Itan kukisi, lo si http://www.macromedia.com/support/documentation/en/flashplayer/help/settings_manager.html.
Ohun Elo Ikojo Silverlight.. Ayelujara tabi ohun elo ti o nlo imo ero Microsoft Silverlight naa ni agbara lati se itoju data nipa lilo Ohun Elo Ikojo Silverlight. Lati ko nipa sisakoso tabi di iru ikojo yii, losi Silverlight.
Microsoft gba orisii irohin kii o le sisẹ daradara ki o sile fun ọ ni ọja ti o dara, isẹ ati iriri ti a le fun ọ.
A gba irohin nigba ti o ba forukọ sile, wọle tabi lo ojula ati isẹ wa. A tunle gba irohin lati ile isẹ miiran.
A n gba irohin yii ni orisii ọna, pẹlu fọọmu ojula, imọ erọ bii kukisi, iwvle si ojula ati lọmulọmu ori komputa rẹ ati ohun elo miiran.
Microsoft gba orisii irohin kii o le sise daradara ki o sile fun ọ ni ọja ti o dara, isẹ ati iriri ti a le fun ọ. Lara irohin yii ni o fun wa taara. Omiiran ni a rigba nigba ti a wo bi o se nlo awọn ọja ati isẹ wa. Awọn miiran wa lati awọn orisun miiran ti a le lopọ pelu data ti a gba taara. Lailani orisun naa, a gbagbọ pe o se Pataki lati lo irohin naa pẹlu isora ati lati ran ọ lọwọ mu asiri rẹ wa bẹẹ.
Ohun ti a gba:
A nlo orisii ọna ati imọ erọ lati gba irohin nipa bi o se nlo ojula ati isẹ wa, gẹgẹbi:
Microsoft nlo awon iwifun ti a gba lati sise, mu dagba ati sodi teleni awon oja ati ise ti a nse.
Atunle lo iwifun yii lati ba o soro, fun apeere, siso fun o nipa akoto ati imudagba aboo re.
Atunle lo iwifun yii lati seranwo mu awon ipolowo ti o nri se daradara sii.
Microsoft nlo awon iwifun ti a gba lati sise, mu dagba ati sodi teleni awon oja ati ise ti a nse. Iwifun ti a gba nipase ise Microsoft kan ni a le somo iwifun miiran ti a gba lati ise Microsoft miiran lati fun o ni iriri eleni nipa ibasepo wa. Atunle se afikun eyi nipa iwifun lati ile ise miiran. Fun apeere, alelo ise lati ile ise miiran lati ranwa lowo lati mo nipa gbogbo agbegbe ti o da lori adiresi IP re lerongba lati se eto ise eleni kan fun agbegbe re.
Atunle lo iwifun yii lati ba o soro, fun apeere, siso fun o nipa igba ti ise gbigba iforuko sile re yoo tan, jije ki o mo akoko ti eto aabo yoo wa tabi igba ti o ye ko se amulo jije ki akoto re wa loju ise.
Microsoft maa n seto opolopo ojula ati ise wa lofe nitori won kin ipolongo lehin. Ki awon irufe ise yii le wa ni gbogboogbo, iwifun ti a gba le wulo fun mimu ipolongo ti o ri gberu ki won o si wulo fun o.
Ayafi bi a se la kale ninu oro asiri yii, a ko ni se afihan iroyin nipa re fun eniketa laigba ase lowo re.
Jowo wo Awon Iroyin Asiri to se pataki fun alaye nipa igba ti a le pin iroyin, pelu awon amugbalegbe Microsoft ati alagbata; nigba ti ofin gba laaye tabi lati dahun si ipe isise ofin; lati dojuko iwa jegudujera tabi saabo fun ife wa; tabi saabo fun emi.
Te nibi lati mo iroyin nipa pinpin tabi isafihan iroyin nipa re:
Awon isẹ Microsoft miiran fun ọ lagbara lati ri tabi satunse irohin ojula ẹlẹni rẹ. Lati se iranwo ki elomiran mari iwifun eleni re, wa koko tatẹwọle naa. Awọn ilana lati sayẹwọ iwifun eleni re yoo dale iru ojula tabi ise ti o lo.
Microsoft.com - O le sayewo ki o safikun nipa re lori Microsoft.com nipa lilo si Microsoft.com Profile Center.
ọna Isanwo Microsoft ati ise akoto - bi o bani ọna Isanwo akoto Microsoft, ole fikun tabi safikun iwifuni rẹ ni ibi Isanwo Ayelujara Microsoft nipa titewo ni ‘’Iwifun Eleni’’ tabi isopọ ‘’Iwifun ọna isanwo’’.
Isopo Microsoft - Bi o bajẹ ẹni ti o saforukv sile ni Isopọ Microsoft, ole wọle tabi se atunse iwifun eleni re nipa tite sakoso Isopo Iforuko sile re ni ojula ayelujara ti icrosoft.
Windows Live - Bi o ba tilo ise Windows Live, o le se afikun iwifun re, se ayipada ọrọ ibawọle , ri ara ọtọ ID ti a somọ iwe ẹri rẹ, tabi ki o ti awọn apo kan nipa lilo si Apo iseWindows Live.
Imo Ara’lu Windows Live - Bi o ba tini imọ nipa ẹni ti gbogbo eniyan ri ni Windows Live, o le se atunse tabi sayokuro iwifun ti gbogboogbo nipa lilo si Windows Live profile.
Ipolowo Iwakiri - Bi o ba ra ipolowo iwakiri nipa ipolowo Microsoft, ole sayewọ tabi satunse iwifun rẹ ni ayelujara Microsoft adCenter..
Eto Ibasepo Microsoft - Bi o ba forukọ sile pẹlu Microsoft Partner Program, ole sayẹwo tabi satunsẹ imọ nipa rẹ nipa titẹ Isakoso Apo re ni ori ojula ayelujara ojuse ẹlẹgbẹ .
Xbox - Bi o ba jẹ ẹniti nlo Xbox LIVE tabi Xbox.com, o le sayewo tabi satunse iwifun eleni re, pelu ona isanwo ati iwifun apo re, ato asiri, abo ojula ati ipin data nipa wiwo My Xbox lori Xbox 360 console tabi lori ayelujara Xbox.com. Fun iwifun akoto yan Akoto Xbox mi. Fun ato iwifun miiran, yan Xbox mi, nipa mi lehinna ato abo ojula.
Zune - Bi o bani akoto Zune tabi iforukosile Zune Pass, o leri tabi satunsse iwifun re ni Zune.net (wole, sayewo Zune.net e lehinna Akoto Mi tabi nipase lomulomu Zune, (wole, sayewo Zune tag re lehinna Akoto Mune.net
Bi o bajẹpe o kole wole si data re ti ojula Microsoft gba tabi isẹ nipase isopo oke, ojula ati isẹ yii le fun o ni ona miiran lati sayẹwo data rẹ. O le kansi Microsoft nipa lilo foomu ojula. A o dahun si ibeere lati sayewo tabi pipa iwifunni eleni re re ni aarin ojo 30.
Nigba ti ojula Microsoft tabi ise re ba sakojo irohin ọjọ ori, koni faye gba awọn olulo to wa labe ọdun 13 tabi gbasẹ lọwọ obi tabi alagbatọ ki awọn ọmọ to le lo.
Nigba ti a ba funni l’asẹ, akoto ọmọ naa lao maa se bi ti awọn akoto miiran, yoo si le baa wọn olulo miiran sọrọ.
Awọn obi lese ayipada tabi di aye gẹgẹbi ati so sinu ọrọ asiri yii.
Nigba ti ojula Microsoft tabi isẹ rẹ ba sakojo irohin ọjọ ori, koni faye gba awon olulo to wa labẹ ọdun 13 tabi ki o ni ki won gba asẹ lọwọ obi tabi alagbatọ ki won to leloo. Ako ni mọọmọ ni ki ọmọ ọdun labẹ 13 ki o fun wa ni iwifun ju eyi ti o yẹ lati lo isẹ wa.
Nigba ti a ba ti gbasẹ, a o mu akoto ọmọ naa bii ti akoto awọn iyooku. Omo naa maa ni aye si awon isẹ ibanisoro bii emaili, ifijisẹ lọọgan ati isẹ ojula bọọdu, o si le baa wọn ẹlomiiran ti o jẹ olulo lati oniruuru ọjọ ori.
Obi le se ayipada tabi fagile ipinnu akoko ti isẹ, ki wọn gbe yẹwo, tunse tabi ki wọn beere fun iyokuro iwifun awọn ọmọ wọn. Fun apẹẹrẹ, lori Windows Live, obi lelo si Akoto wọn, ki o tẹ ‘’Igbaye Obi".
Opo ipolongo ojula ti Microsoft ati ise ni a safihan lati odo Ipolowo Microsoft. Nigba ti a ba se afihan ipolongo ojula fun o, a o mu okan tabi ju bee lo kukisi ki a le da komputa re mo nigba ti a ba fi ipolongo han fun o. Fun igba die, a le gba irohin lati ojula nibi ti a fi ipolongo ranse si ki a silo irohin naa lati pese ipolowo ti o ye.
O le ma gba irufẹ ipolongo mọ lati odo Ipolongo Microsoft nipa lilo si ojuwe ijade..
Opo awon ayelujara ati ise ojula wa ni ipolowo kii lehin
ọpọ ipolongo ojula ti ayelujara Microsoft ni Ipolongo Microsoft safihan. Nigba ti a ba safihan ipolowo ojula fun ọ, ao mu okan tabi jubẹẹlo tabi kukisi pupọ sori komputa re ki o le da kọmputa rẹ mọ ni gbogbo igba ti a ba fi ipolowo ransẹ si ọ Nitori a mu ipolowo si oju ayelujara re pelu gegebi iru awọn ipolongo ati awon elegbe akede wa, a le se akojọ iwifun ni orekore si orisii ojuwe, akonu ati ipolongo rẹ, tabi awọn elomiran ti o nlo kọmputa re, bewo tabi yewo. A nlo iwifun yii fun orisii idi, fun apeere, o n ranwa lọwọ lati rimọ daju pe o ko ri iru ipolongo kanna ni gbogbo igba A tun lo iwifun yii lati ranwa lọwọ lati yan ati safihan irufẹ ipolongo kan ti a ro pe yoo se o lanfanni
O le maa gba ipolongo ti a yan mo lati odo Ipolongo Microsoft nipa lilo si oju ewe ijade.. Fun iwifun si nipa bi Ipolongo Microsoft se n gba iwifun, jọwọ ri Oro ikoko Ipolongo Microsoft.
Atun faye gba ipolongo ilẹsẹ kẹta, pelu awọn nẹtiwọki ipolongo miiran, lati se ipolongo lori ojula wa. Ni ona miiran, awon ilese kẹta yii le fi kukisi si ori kọmputa rẹ. Awon ilese wọnyi niyii, sugbọn wọn ko din ni: 24/7 Real Media, adblade, AdConion, AdFusion, Advertising.com, AppNexus, Bane Media, Brand.net, CasaleMedia, Collective Media, InMobi, Interclick, Jumptap, Millennial Media, nugg.adAG, Mobclix, Mojiva, SpecificMedia, Tribal Fusion, ValueClick, Where.com, Yahoo!, YuMe, Zumobi. Awon ilesẹ wonyi le fun ọ ni aye lati jade kuro ni ipolongo ti o dale kukisi wọn. O le ri iwifun si nipa titẹ lori oruko ile-ise loke ki o si tẹle isopọ si oju ayelujara ti ile ise kọọkan ọpọ wọn ni o je ọmọ egbe ti Netiwoki agbekale ipolwo tabi ibasepo ipolowo Digita, eyi ti onikaluku pese ọna ti o rọrun lati jade ninu idojukọ ipolowo lati ọdọ ile ise ti o kopa.
O le se idaduro ipolowo e-maili ojo iwaju ni ojula Microsoft ati ise nipa titele ilana imoran ti a la sile ninu e-maili ti o gba. O da lori iru ise, otun le ni anfanni lati yan ketekete nipa ipolowo e-maili ti o gba, ipe telifoonu, ati iwe ifiranse lati ọdọ ojula Microsoft kan tabi.
Bi o ba gba e-maili ipolongo lati odo wa ti o si fe dawo gbigba yii duro lojo iwaaju, o le se eyi nipa titele ilana itoni ninu ifiranse naa.
O da lori iru ise, otun le ni anfanni lati yan ketekete nipa ipolowo e-maili ti o gba, ipe telifoonu, ati iwe ifiranse lati ọdọ ojula Microsoft kan tabi ise nipa lilo ati wiwole si awọn oju ila wọnyii:
Yiyan yii o kan isafihan ipolongo ojula: jọwọ lọ si apa "Isafihan Ipolongo (Jade)’" fun iwifunni si lori ọrọ yii. Tabi yala wọn ni fisẹ pẹlu gbigba isẹ iabara-eni sọrọ ti o pọn dandan ti a ri gẹgẹ bi isẹ Microsoft kan, eyi ti o le gba lorekore ayafi ti o ba pa ise naa rẹ.
Akoto Microsoft (eyi ti a mo si Windows Live ID ati Iwe irina Microsoft tele) je ise ti o fun laaye ati wole si oja Microsoft, ayelujara ati ise, ati awon aayo elegbe Microsoft. Nigba ti o ba seda akoto Microsoft, a o ni ko fun wa ni awon iwifun kan. Nigbat ti o ba wole si ojula tabi lo ise akoto Microsoft re, a o gba awon iwifun kan lati da o mo lassoju ojula ati ise, lati dabobo o lowo ilo aito, ati lati dabobo ilo daradara ati abo ise akoto Microsoft. A fi awon iwifun kan ranse si ojula tabi ise ti o ti wole si akoto Microsoft re.
Lati se ayewo miiran nipa akoto Microsoft, ati bi a se seda ati lo akoto Microsoft, bi a se satunse akoto iwifun, ati bi a ti n gba ati mu duro iwifun to jomo sisagbekale akoto Microsoft, jowo te lati mmo si.
Akoto Microsoft (eyi ti a mo si Windows Live ID ati Iwe irina Microsoft tele) je ise ti o fun laaye ati wole si oja Microsoft, ayelujara ati ise, ati awon aayo elegbe Microsoft Lara re ni oja, ayelujara ati ise gegebi awon wonyii:
Iseda akoto Microsoft.
Ole seda akoto Microsoft nibi nipa sise ipese adiresi e-maili re, oro iwole ati omiiran ‘’pe iwo loni akoto’’, gegebi adiresi e-maili miiran, nomba ibanisoro, ibeere ati idahun asiri. A o lo ‘’pe iwo loni akoto’’ fun idi aabo nikan – fun apeere, lati da o mo nigba ti o ko ba le lo akoto Microsoft re ati iranwo ti o nilo, tabi lati tun oro iwole re da, bi o ko ba le wo adiresi e-maili ti o room akoto Microsoft re. Awọn ise miiran le pelu afikun abo, ni ọna yii, a le ni ki o fun wa ni nọmba abo miiran Emaili ati oro iwole ti o lo lati foruko sile fun akoto Microsoft re je ‘’iwe eri’’ ti waa lo lati fi jeri pelu netiwoki re Lakotan, nomba 64-bit ID ara-oto ni a so mọ iwe eri re ti a o lo lati da iwe eri re mo ati iwifun miiran.
Nigba ti o ba seda akoto Microsoft, a o tun ni ki o fun wa ni awon iwifun adamo re: Okunrin ni o tabi obinrin; orile-ede;ojo ibi; ati koodu ifiweranse si. A le lo ojo ibi lati ri daju pea won omo gba ase ti o to lati odo obi tabi alagbato lati lo akoto Microsoft, gegebi ofin ti wi. Ni afikun, iwifun adamo yii ni ero ipolongo ojula wan lo lati fun o ni ipolongo nipa oja ati ise ti o le wulo fun, sugbon ero ipolongo ojula wa kii gba oruko tabi iwifun ibapade re. Ni oro kan, ero ipolongo wa koni beeni kii lo iwifun ti yoo mo o taara (bii oruko re, adiresi emaili ati nomba ibanisoro). Bi o bay an lati ma gba ipolongo eleni, ole foruko sile nipa lilo akoto Microsoft ti o yan nipa lilo si oju ewe yii ti o jepe nigba ti o ba wole sinu ayelujara tabi ise pelu akoto Microsoft re, ero ipolongo wa o ni fun o ni ipolongo teleni kan. Fun iwifun si nipa bi Ipolongo Microsoft se n gba iwifun fun ipolongo, jọwọ ri Oro ikoko Ipolongo Microsoft.
Ole lo adiresi emaili ti Microsoft pese (bii awon ti live.com, hotmail.com, tabi msn.com gbeyin re) tabi adiresi emaili ti egbe keta pese (bii eyi ti o pari pelu gmail.com tabi yahoo.com) nigba ti o ba n foruko sile fun akoto Microsoft.
Nigba ti o ban se eda akoto Microsoft, a o fi emaili ranse si o eyi ti yoo so pe ki o so boya iwo ni o ni adiresi emaili ti a sopo pelu akoto Microsoft re. Eyi wa fun lati mo otitọ adiresi e-maili ati lati dena lilo adiresi e-maili re lai gbaye lowo eniti o nii. Nitori naa, ao lo adiresi emaili naa lati fi ibasoro ti o jomo ilo oja Microsoft ati ise sowo si o;atun le fi emaili ipolowo nipa oja ati ise Microsoft sowo si o gegebi ofin se so. Fun iwifun nipa sisakoso gbigba ipolowo ibasoro, jowo losi Ibasoro.
Bi o ba gbiyanju ati foruko sile fun akoto Microsoft ti o si wa rip e elomiran ti seda iwe eri pelu adiresi emaili gegebi oruko olulo, o le kansi wa ki o sib ere pe ki olulo miiran yen o yan oruko olulo miiran ki iwo o le lo adiresi emaili re nigba ti o ba n seda iwe eri.
Wiwole sinu lomulomu, ojula tabi ise pelu akoto Microsoft re.
Nigba ti o ba wole si ojula tabi ise nipa lilo akoto Microsoft re, a gba awon iwifun kan lati da o mo fun ojula tabi ise naa, lati dabobo o lowo olulo akoto madaru, ati lati dabobo ilo daradara ati abo fun ise akoto Microsoft. Fun apeere, nigba ti o ba wole, akoto ise Microsoft gba o si fi iwe eri re pelu iwifun miiran sile, awon bii 64-bit nomba ID ara oto ti a yan fun iwe eri re, adiresi IP re, ojula eya brausa re pelu akoko ati deeti. Siwaju si, bi o balo akoto Microsoft lati wole sinu ero ilo tabi sinu lomulomu ti a fi sori ero, ID ara oto ti a mu ni a yan pelu ero; ID ara oto ti a mu yii ni a o fi ranse gegebi ara iwe eri fun akoto ise Microsoft re nigba ti o ba wole sinu ojula tabi ise pelu akoto Microsoft re. Akoto Microsoft naa fi awon iwifun yii ranse si ojula tabi ise ti o ti wole si: Nomba ID ara oto ti o fayegba ojula tabi ise lati mo boya iwo naa ni enikan naa ti o wole wa-leralera si eyi to tele;eya nomba ti a yan fun akoto re (nomba tuntun ni a funo nigba igbakigba ti o ba se ayipada iwifun iwole re); boya a timo adiresi emaili re; tabi ati yo akoto re danu.
Awon ojula tabi ise egbe keta ti o gba o laye lati wole sinu akoto Microsoft re beere adiresi emaili re ki won le fun o nise won. Ni iru ipo yii, nigba ti o ba wole, Microsoft yoo pese adiresi emaili re sugbon kii se oro iwole re si ojula tabi ise. Sugbon, bi o ba seda iwe eri re pelu ojula tabi ise naa, ole ni idinwo imulo si iwifun ti o somo iwe eri re ki o le ran o lowo lati se atunto oro iwole tabi pese ise iranwo miiran.
Bi o ba gba akoto re lati odo egbe keta, bii ile eko, ibise, olupese ise ayelujara, tabi alabojuto isakoso agbegbe, egbe keta yii le ni ase lori akoto re, pelu eto lati satunse oro iwole re, isayewo ilo akoto tabi data eleni re, ka tabi safipamo ekun akoto re, ati fifagile akoto re. Ni iru nnkan wonyii, o wa labe Ibasepo ise Microsoft ati si afikun ase lilo lati odo irufe egbe keta naa. Bi o ba je alabojuto isakoso akonu kan ti o si ti fun awon olulo re ni akoto Microsoft, iwo ni o wa isakoso fun gbogbo ohun ti o sele labe awon akoto bee.
Jowo mo wipe ojula ati ise ti o nlo fun o laye lati wole pelu akoto Microsoft re le se amulo tabi pin iwifun eleni ti o pese fun won gegebi won se ko sinu oro asiri won. Sugbon, won le pin nomba ID ara oto ti o fun won nipa ise akoto Microsoft pelu egbe keta nikan kii won le se amuye ise tabi ibasepo ti o le ti beere. Gbogbo ojula tabi ise ti o lo akoto Microsoft ni o gbodo ni ifiranse eleni alasiri, sugbon ako sakoso tabi bojuto awon asiri ori ojula, ise asiri won yoo si yato. O gbọdọ fara bale sayewo ọrọ asiri ojula kọọkan ti o wọle si ki o le mo bi ojula tabi ise kọọkan yoo se lo iwifun ti won gba.
O le ri awọn iwifun eleni re nipa lilo si akoto. Ole se ayipada inagije re bi akoto Microsoft re o ba pelu akoonu ti a nse akoso. Ole se ayipada oro iwole, adiresi e-maili miiran, ati ibeere ati idahun ikoko re nigbakugba. Otunle ti akoto , Microsoft re pa nipa lilo si akoto, lehinna ‘’ti akoto re’’ Bi akoto re ba wa ni akoonu isakoso, bi a ti salaye loke, o le ni ona miiran ti a le fi ti. Jowo mo wipe bi o ba je olulo MSN tabi Windows Live, bi o balo si akoto, ale da o pada si akoto fun awon ojula.
Fun alaye sii nipa akoto Microsoft wa ni akoto ayelujara Microsoft.
Tubomosi i nipa
O o ṣawari afikun ifitoileti ipamọ ti o le (tabi le ma) ri ti oṣe pataki. Opolopo ninu eyii nṣafihan irufẹ iṣe ti o wọpọ ti a fẹ ki o mọ nipa ṣugbọn ti a ko rope o ṣe pataki lati fihan ninu gbogbo gbólóhùn ikokowa. Awon kan lara eyi kan nsọ bi o ti jẹ (fun apẹẹrẹ, a o ṣe afihan ifitonileti bi ofin ba beere rẹ), ṣugbọn awọn agbẹjọro wa sa jẹ ki a sọ naa. Jọwọ fi sọkan pe ifitonileti yii kiiṣe gbogbo apejuwe ìṣe wa - eyi niafikun siomiran, awọn ifitonileti pataki wa ninu gbólóhùn ikokofun ẹyo àbájáde Microsoft ati ilo iṣẹ.
Loju ewe yii:
Sise alabapin tabi Iṣafihan Ifitonileti Ara Eni
Lafikun si pipin yoowuti a ṣalaye ninu gbolohun ikokofun abajade tabi iṣẹ ti o nlo, Microsoft le pin tabi ṣafihan ifitonileti ara eni:
Atunle ṣe alabapin tabi iṣafihan ifitonileti ara ẹni, pẹlu akoonu ibanisọrọ rẹ:
Jọwọ kiyesii pe ojula wa le ni isopọ ojula ẹgbẹ kẹta eyi ti ilana idabobo wọn le yatọ si ti Microsoft. Bi o ba se agbekale ifitonileti ara ẹni lori eyikeyii ninu awon ojula yen, iṣakoso ifitonileti rẹ wa lati gbolohun ipamọ ojula naa. A rọ ọ lati ṣe ayẹwo gbolohun ipamọ ojula yoowu ti o ba bẹwo.
Idaabobo ààbò Ifitonileti Ara Ẹni
Microsoft faraji ni idaabobo aabo ifitoniletiaraẹni rẹ. A nlo oriṣii ọna aabo ati ilana ti imo ero lati ran ọ lọwọ lati daabobo ifitonileti ara ẹni rẹ lati ọwọ ẹniti akofayegba, lilo tabi ifihan. Fun apẹẹrẹ, a nṣe ifipamọIfitonileti ara ẹni ti o pese lori ẹrọ kọmputa ti o ni idiwọn lilo ti o si wa labẹ ohun iṣakoso. Fun apẹẹrẹ, a nṣe ifipamọIfitonileti ara ẹni ti o pese lori ẹrọ kọmputa ti o ni idiwọn lilo ti o si wa labẹ ohun iṣakoso.
Bi a ba lo ọ̀rọ̀ aṣínà lati ṣe iranwọ idaabobo akọọlẹ re ati ifitonileti ara ẹni, ojuṣe rẹ ni lati fi ọ̀rọ̀ aṣínà rẹ pamọ. Maṣe se alabapin re. Bi o ba nṣe alabapin kọmputa, o gbọdọ maa ṣe atẹjade ki o to kuro loju ila tabi iṣẹ lati dabobo iwọle si ifitonileti rẹ ni lilo.
Nibi ti a fi Ifitonileti Pamọsi ati Imulo
Ifitonileti ara ẹni ti a gba lori ojula Microsoft ati iṣẹ ni a le fi pamọ ati ṣamulo ni orilẹ ede Amẹrika tabi ni orilẹ ede miran nibi ti Micosoft tabi amugbalẹgbẹ, ẹka tabi olupese iṣẹ ti n ṣakoso ohun elo. Microsoft maa ntele Ilana ti U.S.-EU Safe Harbor ati ti U.S.-Swiss Safe Harbor gege bi Ile Ise fun Eto Okoowo ti Amerika ti la a kale nipa gbigba, lilo, ati igbamu awon data lati agbegbe European Economic Area, ati Switzerland. Lati tubo mo si i nipa eto Safe Harbor naa, ati lati wo iwe ase wa, jowo kan si http://www.export.gov/safeharbor/.
Gẹ́gẹ́ bí ara ìlọ́wọ́sí Microsoft nínú ètò Safe Harbor, a nlò TRUSTe, olùkópa kẹta tí ó dá dúró, láti yanjú àwọn aáwọ̀ tí o ní pẹ̀lú wa tí ó ní íse pẹ̀lú àwọn ìlànà àti ìse wa. Tí o ó bá fẹ́ láti kàn sí TRUSTe, jọ̀wọ́ se àbẹ̀wò sí https://feedback-form.truste.com/watchdog/request.
Microsoft leni ifitonileti ara ẹni rẹ lọwọ fun oriṣii idi, gẹgẹbi titẹle ilana ofin wa, ipari ija, iridaju lilo ifimọṣọkan, fun igba ti o yẹ lati pese iṣẹ. Lati kekoọ nipa iwọle si ifitonileti ara ẹni rẹ, kansi Dide ibiIfitonileti Rẹ.
Ayipada Awon Gbólóhùn Ìpamọ́ Wa
A o maa ṣe atunṣe awon gbolohun ikoko wa lati ṣafihan ìjábọ̀ onibara ati ayipada iṣẹ wa. Nigba ti a ba ṣe ayipada gbolohun, a o ṣe atunyẹwo ọjọ ''Iṣafikun ti okẹhin'' lori gbolohun naa. Bi awonayipada ohun bawa ninu gbolohun naa tabi ni bi Microsoft yoo ṣelo ifitonileti ara ẹni rẹ, a o fi to ọ leti nipa iṣafihan Ifitonileti irufẹ re ki wọn to waye tabi fifi akiyesi ranṣẹ si ọ taara. A ro o lati ṣe agbeyẹwoawon gbolohun ipamọ loorekoore fun awon ohun ti a npese ati iṣẹ ti o lo lati kekoo nipa bii Microsoft ṣe n daabobo ifitonileti rẹ.
Bi a o ti kansi wa
Microsoft Privacy, Microsoft Corporation, One Microsoft Way, Redmond, Washington 98052 USA
Lati ri ẹka Microsoft ni orilẹ ede tabi ẹkun rẹ, wo http://www.microsoft.com/worldwide/.
Asiri Atinuda
Abo nile
Trustworthy Computing